HYMN 14

Mimo, Mimo, l’Olorun wa,
O boju Re wo sara awa elese
Iyanu nise Re gbogbo,
Mimo, l’Olorun wa Mimo,
Pelu iteriba l’awon angeli nkorin
Orin iyin didun,
Baba, Omo, Emi Mimo,
Ore-ofe Re gbogbo po,
Lori Ijo Mimo.	Amin 

English »

Update Hymn