1. Jesu wa, oluwa olugbala,
Si lekun anu re fun wa
K’awon ogun orun
Re wole wa,
Halleluyah ni orin wa
Halleluyah, Halleluyah,
Halleluyah mbe lenu wa.
2. Maleka mimo oga Ogun
O mbe lenu ‘bode orun
Lati ba gbogbo emi esu wi
Ka le riye gba lojo na,
Jehovah mimo mbe
Jehovah mimo mbe
Jehovah mimo mbe
3. Kristi wa duro lori apata
O npe wa ka duro lor’apata
Enit’ o ba duro lori re
Ni yio ri, Kristi ni kehin
Jesu wa Mimo ni
Kristi wa Mimo ni
E o ri Jesu nikehin. Amin