HYMN 186

1.	Ijo Mimo e ho f’ayo,

	Ojo ayo wa si ti de,

	Jesu ku, O si ye e titi aiye,

	Lati mu wa ye e titi aiye,

Cr:	A! Jesu ti ye e, O ti joba,

	O joba titi aiye,

	Ade Re ko lala fiwe,

	T’afewa, Orun, Osupa se.


2.	Ka mu fe Re se toto toto,

	Ki ‘leri ayo na le se,

	K’ogba ajare Re le kun,

	F’eso ife atokan wa,

Cr:	A! Jesu ti ye e, O ti joba,

	O joba titi aiye,

	Ade Re ko lala fiwe,

	T’afewa, Orun, Osupa se.


3.	Ki gbogbo ipa Esu le tu,

	T’o fi de wa nigbekun ri,

	Ati f’owo agbara tu wa,

	Ninu igbekun esu.

Cr:	A! Jesu ti ye e, O ti joba,

	O joba titi aiye,

	Ade Re ko lala fiwe,

	T’afewa, Orun, Osupa se. Amin

English »

Update Hymn