HYMN 207

Duru wura nke tantan,

Yi agbala Orun ka,

Adun l’ohun orin won,

Ti awon Angeli nko,

Pelu iyin nla nla,

Nwon nte ori won ba

Pelu ibowo nla nla,

Nwon si nf’ogo f’Oba Orun,

Ogo Ogo, iyin, fun Baba,

Eleda Orun ati at’aiye,

Halleluya Halleluya

Hossanah l’ohun orin won

Halleluya Halleluya

Hossanah l’ohun orin won. Amin

English »

Update Hymn