HYMN 230

1.  Emi Mimo

     sokale wa O,

     KO wa fun wa

     Iagbara.


2.  Jesu Oluwa o,

     sokalewa O,

     KO wa fun wa

     lagbara.


3.  Adaba Mimo, sokale wa o,

     Ko wa fun wa

     lagbara.


4.  Maleka Mimo

     sokale wa o,

     Ko wa fun wa

     lagbara.


5.  Ogun orun Mimo,

     sokale wa o,

     Ko wa fun wa

     lagbara.


6.  Emi Mimo, Sokale wa o

     Ko wa fun wa 

     lagbara. Amin

English »

Update Hymn