1. AGBARA mo ti sokale wa,
Agbara mo ti sokale wa,
Agbara mo ti sokale wa,
To ntan lode Orun.
2. Enyin omo ‘Jo Mimo,
e mura,
Enyin omo ‘joMimo
e mura,
Enyin omo ‘joMimo,
e mura,
Ke gba bukun eyi.
3. Agbara to poju eyi lo,
Agbara to poju eyi lo,
Agbara to po ju eyi lo,
Yio sokale fun nyin. Amin