HYMN 280

1.  AWA n’Ijo Mimo Aladura,

     Ijo Mimo dara, Jesu Baba wa

     f’ohun rere sile,

     Inu wa si dun Halleluya.


2.  Awa nyo ninu Jesu,

     n’Ijo Mimo,

     Jesu mbe lehin wa,

     Ohun gbogbo t’awa
 
     mbere lowo Re,

     O si ti fun wa Halleluya.


3.  Awa ni Ijo Mimo loke Orun,

     Ijo Mimo mbe,

     Awon Angeli nyo peluwa,

     Ara wa si ti ya Halleluya. Amin

English »

Update Hymn