HYMN 282

1.  BABA wa, Omo sokale,

     Lori ‘te Mimo Re,

     Lati mu ibukun ati

     Ogo f'omo Re


2.  Baba orun mbe ninu ayo,

     Pelu awon Angeli,

     Jesu Kristi, Baba wa

     nyo pelu won.


3.  E ke Hossanah si Oba wa,

     Oluwa Olubukun,

     T’ombe ninu Tempili re 

     Mimo, O Si nyo.


4.  Baba wa Orun sokale sire,

     Pelu awon Ogun Orun

     Awon Si busi ayo

     fun Ijo Mimo yi.


5.  E ke Halleluya , s'Oba wa

     Awa Elese yi.

     Nitoripe Emi Oluwa

     mbe lotito.


6.  Ka fope fun Olorun wa,

     Fun ise Re gbogbo

     Iyanu ni ise Re, 

     lori awa eda.


7.  'Jo Celestial, Ijo Mimo

     T'Emi oluwa bukun,

     Nitori ese aiye po,

     l'ase mu yi wa.


8.  Kawa elese yiwa pada,

     T’ori idajo wole,

     lo ri awon eni ibi,

     l'emi o se yi. Amin

English »

Update Hymn