HYMN 284

1.	Igbala de loni,

	Enyin Ijo Mimo,

	E gbo bi ipe tin dun,

	Ipe Odo aguntan 


2.	Ipe na dun kikan,

	E mase jafara,

	Sa sala f’emi Re

	Ka koko to koja.


3.	Olugbala na de,

	Lati ra wa pada

	E kanu fese yin,

	Ti nda eru ba yin. Amin

English »

Update Hymn