HYMN 288

1.	Igba ironu de,

	Aiye, e gbe orin yi,

	Orin Mimo t’Orun,

	Aiye, e gbe orin yi,

	E korin s’Oba Oluwa. 


2.	Enyin Ijo Mimo,

	E korin s’Oba Oluwa,

	E wo Ade ti Baba,

	Sokale t’Oba Alade. 


3.	Enyin Ijo Mimo,

	E gba Ade yi sile,

	Awon to yan falade,

	To se tan lati sin. 


4.	Aiye mo ti se tan,

	Lati se nyin logo,

	Eni to ba mura,

	Ogo na ti se tan.


5.	Ijo Mimo temi,

	Lat’Orun lo ti wa,

	Awon to sin nibe,

	Ninu ‘mole ‘won wa.


6.	Awon angeli ni,

	Se ranse Mi logo,

	Iranse ti aiye yi,

	E mura lati sin.


7.	Imole na se tan,

	O sin tan s’aiye,

	Awon to wa lokunkun,

	Nwa sinu Imole. Amin

English »

Update Hymn