HYMN 303

1.	Awon Angeli yo lodo Baba,

	Awon Angeli yo lodo Baba,

	Ise ti Baba ran wa,

	Lawa yio ma se,

	Ha! Ha! Ha! Halleluya,

	Ha! Ha! Ha! Halleluya,

	Ha! Ha! Ha! Halleluya,

	Lorin wa yio je.


2.	Inu ayo la wa lodo Baba,

	Inu ayo la wa lodo Baba,

	Ayo ti Baba fun wa,

	Ki yio de opin,

	O! O! O! Orin segun,

	O! O! O! Orin segun,

	O! O! O! Orin segun,

	Lawa nko s’aiye. Amin

English »

Update Hymn