1. Mo yin Oba mi,
Moyin O loke,
E gbe Oruko Re ga
titi laiye.
2. E yin Oba Imole,
E wole ni waju Re,
E bere Oruko Re,
Yio fl fun wa.
3. E wo Oba Imole,
Ti mbe pelu wa,
Yio wa pelu wa
dopin aiye. Amin