HYMN 378

O YE wa, ka f’ope fun Oba Oluwa

E ja k’a wa f’ope fun Oluwa,

Era  ile won dupe,

Yarin okun won dupe,

E je ka wa na dupe,

Hallelujah f’oluwa

E je ka yin Oluwa. Amin

English »

Update Hymn