HYMN 384

EJE ka f’ope fun Baba,

Orun, Osupa wa ninu imole,

Enia ko ni agbara,

L’ori Ijo Mimo yi,

Oba Orun lo fi ranse,

Awon angeli nyo, won nyo,

Won nyo ninu Kristi,

Awon angeli nyo, won nyo,

Won nyo ninu Kristi. Amin

English »

Update Hymn