1. ANGELI Oluwa,
E sokale ninu iponju wa,
Angeli Oluwa,
E sokale ninu iponju wa.
2. Ajagun segun ode Orun,
E sokale ninu iponju wa,
Angeli Oluwa,
E sokale ni mimo julo.
3. Awon Oso, awon Aje,
Awon onisegun,
olorisa won yi wa ka,
Angeli Oluwa,
E sokale ninu iponju wa. Amin