HYMN 463

OLUWA duro, o nwo wa,

Yio gba wa lowo aiye,

Michael Mimo gbeda re soke,

Lati segun fun wa,

Lati segun fun wa,

Lati segun fun wa,

Ka gbe okan s’oke,

Ka gba Oluwa gbo. Amin

English »

Update Hymn