HYMN 467

1.  WA segun Jesu Kristi,

     Fun awa iranse Re,
  
     Larin ota lawa wa,

     Baba wa segun.


2.  Eyini gbagbo wa pe,

    Ire yio segun iku,

    Wa segun oni funwa,

    Baba wa segun.


3.  Eyi ni gbagbo wa pe,

     Ire yio wa pelu wa,

     Mafi ‘ranse Resile,

     Baba wa segun.  Amin

English »

Update Hymn