HYMN 469

1.  K'OBA Mimo ko sokale,

     Ko wa gba wa loni,

     K’Oba Mimo ko sokale,

     Ko wa gba wa loni.


2.  Ninu ijo Mimoyi loni,

    Kowa d’emi gigun si fun wa,

    Ninu ljo Mimo yi loni,

    Kowa d’emi gigun si. Amin

English »

Update Hymn