HYMN 470

OBA Edumare, Oba toto,

Oba Edumare, Oba toto,

Atobi julo ninu awon orun

Oba aseyi owu, Oba awimayehun

asoro matase,

Oba agbenu omo enia

f’ohun, Oba ogo,

Agbara igbega, Ire l’oni,

Agbara idalare ire lo ni,

Agbara itota mole ire loni

Gbe wa ga loni o Oba ogo,

Gbe wa ga loni o, Oba ogo. Amin

English »

Update Hymn