HYMN 51

1.	Oluwa, Oluwa, Oluwa Olugbala

	Awa Ijo Mimo la’torun wa.

	Wa f’anu gbo ti wa.

2.	Olugbala, Oluwa Olusegun,

	Awa omo Re nkepe e O,

	Wa gbo adura wa.

3.	Enyin Ogun Mimo la’torun wa,

	E wa lati sokanle sinu,

	Ijo Mimo yi.

4.	Enyin Angel’ e ho iho ayo

	S’emi Oluwa mbe pelu 	enyin,

	Ijo Mimo yi.

5.	Fun wa lagbara sinu Ijo 	Mimo yi

	Kawa lelo fun Ogo Re,

	Laiye ainiekun.

6.	Mura si ‘se ‘ise Olugbala

	Nitori Ade Iye mbe 	f’enyin,

	Lojo ikehin. Amin

English »

Update Hymn