HYMN 526

1.	Ona to ‘lorun ngba soro,

	Lati se Ise Re,

	Ona Re enikan ko mo,

	Awamaridi ni. 


2.	Alaigbagbo won yio sina,

	Won ko ‘se Oluwa,

	Sugbon awa to gb’Oluwa gbo,

	A ki yio pofo laiye. Amin

English »

Update Hymn