HYMN 533

1.	Ayo, ayo, ayo yio wa,

	Ninu Ijo Mimo yi,

	Ekun, wahala yio dopin,

	Ninu Ijo Mimo yi.


2.	Wahala on iponju,

	Mo ti ko won sile,

	Gbogbo enyin Ijo Mimo,

	E yo, e yo, e yo.


3.	Ogo Mi lo si je Ori,

	Ninu Ijo Mimo,

	Ogo ti awon orun ri,

	Ti won si yo titi.


4.	Eni to ba si le sin Mi,

	Yio si ri ogo na,

	Ogo na temi si soro,

	Yio si ni igbala.  Amin

English »

Update Hymn