HYMN 537

1.	Ma foya ni apa Jesu,

	Ko si ohun eru kan,

	Ina ti njo ko le sunmo o,

	Ogun esu ti di wiwo mole,


2.	Mo ro mo agbelebu Re,

	Mo ka ohun gbogbo sa san,

	Ma beru ire okan mi,

	Ayo mbe ninu eje Jesu.


3.	Emi ko ni ju o sile,

	Jesu Olugbala mi,

	Ninu Re ni iye mi wa,

	Ire ni Olugbala mi.


4.	Ijo Mimo bu si ayo,

        Oko iyawo wa pelu Re,

        Ayo ni tire si ma yo,

        Ade iye na yio je tire.  Amin

English »

Update Hymn