HYMN 539

1.	Aiye yi ti wo segbe kan,

	Satani nkiri fun itiju,

	Elese yara wo ‘ko ikehin,

	Ko ma ba je eni ta o feku.


2.	Anu Baba ti nfe dopin,

	Ki o tun gbohun adura mo,

	Rukerudo ajakale arun,

	Ati ‘ponju ti sunmo aiye. 


3.	Baba ko fe egbe elese,

	Beni ko si fe iku won,

	Wa sodo Mi l’OLugbala nwi,

	Emi yio si gba gbogbo yin la.


4.	Gbogbo yin, e po ninu ife,

        Pelu isesi tododo,

        E ma gbadura nigbagbogbo,

        Emi o si wa pelu yin dopin.  Amin


English »

Update Hymn