1. Mo gba O gbo tokantokan,
Mo gba O gbo O,
Mo gba O gbo tokantokan,
Mo gba O gbo O.
Chorus: Mo gba O gbo Olu Orun,
Mo gba O gbo O,
Mo gba O gbo tokantokan
Mo gba O gbo O.
2. Ire lo gbo ti Elijah,
Ire lo gbo ti Hannah,
Ire lo gbo ti Abraham,
Ire lo gbo ti Nebukadinesari
to yi pada si O.
Chorus: Mo gba O gbo tokantokan
Mo gba O gbo O... Amin