HYMN 575

1.	Oluwa ma fi mi se gbagbe

	Ranti mi to ba de joba Re,

	Nibi igbala on ayo gbe wa,

	Nibi igbala aiyeraiye.


2.	Oluwa to loke loni ‘le

	On lo l’Orun to laiye,

	Bo ti wu kile aiye dun to,

	A o faiye sile nigba kan.


3.	Nigbati Maria bi Jesu,

	Awon Amoye wa,

	Gbogbo won wa fori bale fun,

	Nwon si nta Jesu lo re.  Amin

English »

Update Hymn