HYMN 58

E korin, k’e gborin soke,

S’Oba Mimo ko gba wa la,

Ninu Ijo Mimo yi

K’Oba Mimo, ko gba wa la

Ko fun wa laranse,

Kopa wa mo kuro ninu ese,

Ko wa dariji wa. Amin

English »

Update Hymn