HYMN 580

1.	Nigbati fere Oluwa yio dun,

	Ti ise ki o si mo,

	A o pe ohun alaye ‘gun merin wa,

	Lati fi ise won han,

	Ni’waju Olugbala wa,

	Nigbati fere yio dun,
 
        emi o wa nibe, 

Chorus:	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati fere yio dun

	Emi o wa nibe. 


2.	Awa yio ma korin,

	Lati owuro ti ti dale,

	Awa yio ma f’Ogo fun Olorun,

	Olugbala yio ma pe

        gbogbo wa ni Omo rere, 

Chorus:	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati fere yio dun

	Emi o wa nibe. 


3.	Awa olurapada yio ‘fo,

	T’aro ki yio mu wa,

	Lati pade ‘Lugbala Jesu Kristi,

	Awa yio wa ni abe ‘ye Olorun titi aiye,

	Alleluia ni orin wa yio ma je,

Chorus:	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati, fere yio dun, lohun,

	Nigbati fere yio dun

	Emi o wa nibe.  Amin

English »

Update Hymn