HYMN 602

1.	Ayo Oluwa pe titi

	Ayo titi aiye.

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa.


2.	Enyin ogun Orun, e wa

	Ke wa gbase yi se.

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa. 


3.	Enyin aiye, e was a yo,

	E wa sinu oye,

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa.


4.	Aiye, e wa sinu ‘mole

	Irawo meta lo le,

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa.


5.	E wa Oga Ogo, Baba,

	Waiye pelu ikanu,

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa.


6.	Enyin omo Ijo Mimo,

	E tewo ke gba ‘bukun,

Chorus:	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Ninu Ise Re lawa nyo,

	Baba wa sure fun wa. Amin

English »

Update Hymn