1. BABA Baba Orun,
Lo pase fun ‘Jo yi,
Awamaridi ni,
Ise Oluwa wa.
2. Ijo Mimo e yo,
Ninu ‘se Baba yin,
Tologo meta ni,
Ogo foruko Re.
3. Aiye yio si wa yo,
Ninu agbo Kristi yi,
Agutan ti Baba,
Yio kuro ninu egbe. Amin