1. JESU duro niwaju mi,
Ko mi ki nle se ife Re,
Ise to yan mi si,
Fun mi lagbara Re
Ki nle se yi.
Chorus: Halleluya Halluleya
Halleluya lorin mi.
2. Jesu duro niwaju mi,
Ko mi ki nlese ife Re,
Ife t’Olorun fe,
Larin eda gbogbo,
Bi ti Orun.
Chorus: Halleluya Halluleya
Halleluya lorin mi.
3. Oluwosan ni Jesu wa,
Wa wo ‘nu okan wa san,
Emi t’Olorun fe,
Se wa gege bi Ire,
Nu’mole yi.
Chorus: Halleluya Halleluya,
Halleluya Iorin wa. Amin