HYMN 620

1.	Enyin Omo Ijo Mimo,

	E damure nyin giri,

	Ka si le b’awon Angeli,

	Ka Alleluya lojo na,

	Ka si le bo sinu Ayo Oluwa.

Solo:	Damuso fun Baba

        Awamaridi jinle Kabiyesi,

        Jehovah Mimo jowo,

        Ma se le mi lodo Re,

        Nipa ore ofe Re,

        Kinle de be.


2.	Nitori Jesu mbo wa,

	Lati se ‘dajo aiye,

	Yio si kawon ayanfe,

	Lo sodo Baba loke,

	A o si b’awon Angeli k’Alleluya.

Solo:	Damuso fun Baba

        Awamaridi jinle Kabiyesi,

        Jehovah Mimo jowo,

        Ma se le mi lodo Re,

        Nipa ore ofe Re,

        Kinle de be.


3.	Jesu si npada bow a,

	Gegebi bi ole loru,

	Enyin ayanfe Oluwa,

	E je ka mura sile,

	Lati le b’awon Angeli,

	Fo lo sorun.

Solo:	Damuso fun Baba

        Awamaridi jinle Kabiyesi,

        Jehovah Mimo jowo,

        Ma se le mi lodo Re,

        Nipa ore ofe Re,

        Kinle de be.  Amin



English »

Update Hymn