HYMN 634

1.  ESIN Olorun Eleda yin,

     Nitori mo ti fi 'yin joba,

     Lo'rawon eranko aiye,

     Gbati wakati na ba de.


2.  E boju yin w'orun on aiye,

     Lati f'ohun gbogbo fun yin,

     Aiyeyiti npin lo na,

     Etara si ise emi.


3.  Oludena na de,

     Latiwa bere ise yin,

     Fun mi lagbara ati Emi,

     Lati segun Oludena yi.  Amin

English »

Update Hymn