1. OLUSO Agutan, Oluso, Agutan,
Akigbe tantan si yin,
Wipe e yi pada si mi.
2. Ipe anu ni eyi,
T’aiye si npe yin Agutan,
Olugbala lo npe yin,
Wipe e yi pada si mi.
3. Ijo Mimo, Emura,
Fun ‘se nla, mo gbe fun yin,
Eyi ni amure yin,
Ti mo t i pese le e fun yin.
4. Ijo Mimo, e wa gbo,
Ti mo npe tantan si yin,
Ojo ‘kehin na de tan,
Ke le kun u aiye yin. Amin