1. NILE Baba mi l’oke orun,
Opo ibugbe lowa nibe,
Jesu wa nibe, Angeli wa nibe,
Won ‘ko Mimo
Halleluya,
Halleluya Mimo
Halleluya Mimo,
Halleluya Mimo
Halleluya, Halleluya.
2. Agogo kehin fare dun,
Ti gbogbo aiye yio pe jo,
Ta o pin fun Olukaluku,
Gege bi ise owo re.
Emi yio se rere,
emi yio se rere,
Emi yio se rere,
ki nle ri ‘ye,
Emi yio se rere,
Emi yio se rere,
Emi yio se rere,
ki nle ri ‘ye. Amin