1. IJO Mimo, eje ka lo,
Sile mimota wi,
Ile mimo, ile iye,
Ile alafia.
2. Eyin aiye, e teriba,
F’Oba Mimo ta wi,
Olorun Oba aiyeraiye,
Ati Orun Mimo.
3. E je ka mura,
Kawa sin Oba na,
Oba to ga ju aiye lo,
Oba aiyeraiye. Amin