1. E YO ninu ‘se mi,
Ise to logo ni,
Ise t' Emi ba ni nse,
Ise to logo ni,
2. Enyin omo ‘Jo Mi,
E mura ke ri mi,
Aye ti mo wa lohun,
Ipo aiye raiye.
3. Enyin eni mimo,
E mura ke si mo,
Ferese Orunsi sile,
Ewa iye sibi yi.
4. Enyin eni t’ Emi,
E ma se beru aiye,
Abo ti mo fun yin,
Ogo re si de tan. Amin