HYMN 672

1.	Gbo bi ipe na ti n dun lorun

	Jesu duro ni bode orun

	Lati ko awon ayanfe Re

	Lo si ori ite Baba 


2.	Awon Angeli kun fayo

	Nwon nfun fere pelu ayo,

	Baba ka mi mo awon eyi,

	Ki nle ri Jesu lojo na. 


3.	Ore-ofe Re Baba la ntoro

	Agbara ati imisi Orun

	Ko wa ba wag be e lojo oni,

	K’Alleluya le je orin wa.  Amin


English »

Update Hymn