HYMN 680

1.  ENYIN eni temi,

     Emura ke te Ie mi,

     Ise timo waiye wa se,

     se gbogbo aiye ni.


2.  Awon aiyegburo Mi,

     Nigbati mo wa l’Orun,

     Awon na si nreti Mi,

     Igbat’ Emi o fi de.


3.  Ilana ti Baba se,

     Awon eyi ko sile,

     Igbati emi si de,

     Awon'eyi ko mo Mi.


4.  Awon ti o je temi,

     Awon na lo m’ona,

     Nigbati emi wa de,

     Awon lo te e le Mi.


5.  Baba Mi lode Orun,

    Lo ti fun Mi laiye na,

    Awon to bate le Mi,

    Emi yio je ti won.


6.  Enyin agutan temi,

     E mura sesin yin,

     Esin yi yio gba yin,

     Kuro ninu egbe.  Amin

English »

Update Hymn