HYMN 693

1.  WAKATl na de,

     Enyin omo ‘Jo Mimo,

     E mura sile de Baba yin,


2.  Ipe kehin dun,

     T'awon Maleka fun ipe,

     E duro de ore ofe Re.


3.  Eyin Oluwa,

     Oko ikehin de,

     E yo ninu Kristi ‘Jo

     Mimo.  Amin

English »

Update Hymn