HYMN 694

1.	Ka sise fun iwenu mo Emi wa,

	K’Oluwa fi le wa pelu wa,

	Ka sise fun Ijo Jehovah

	Ka si ranti orun mimo,

	Ka sise fun iwenu mo Emi wa,

	Ka si ranti ile nla loke orun,

	Ka sise fun iwenumo Emi wa

	Ka si ranti ile nla loke orun.


2.	K’Oluwa jowo sokale sarin wa,

	Ka wa fi le ri iwenumo,

	Michael Mimo ko ran wa lowo,

	Kuro ninu idanwo aiye,

	Ka wa fi le segun emi esu,

	Ka sise pelu ife mimo,

	Ka wa fi le segun emi esu,

	Ka sise pelu ife mimo,


3.	Asan ni fun enia lati f’okan fun,

	Isura aiye ti yio fo lo,

	O ye ka wa pejo ka sise,

	Ise ti Kristi ran wa,

	Eyi ni yio mu wa gb’ade Ogo,

	Ti Baba se leri re fun wa,

	Eyi ni yio mu wa gb’ade Ogo,

	Ti Baba se leri re fun wa.  Amin



English »

Update Hymn