HYMN 695

1.  NIGBA angeli fun ipe

     Awon oku yio ji dide,

     Awon to sun lododo,

     Yio ri Jesu l’ojo na.


2.  Nigba Gabrieli ba de,

     Pelu orin ayo,

     Baba kawa mo won,

     Kale ri Jesu lojo na.


3.  Michael Balogun wa,

     Sokale pelu ida re,

     Lati segun fun wa,

     Kale ri Jesu lojo na.  Amin

English »

Update Hymn