HYMN 713

1.  B’AGOGO Orun balu,

     Awa Omo Ijo Mimo

     A o duro, a o duro,

     Niwaju re, Niwaju Re.

Chorus: A o duro, niwaju Re,

        A o b'awon angeli korin,

        Ogo, ogo f’Oba wa,

        Halleluya, Halleluya,

        A o duro, o, niwaju Re.


2.  Ijo Mimo e mura,

     E damure nyin giri,

     Nitori, Nitori,

     Bi Jesu bade, awa o duro,

Chorus: A o duro, niwaju Re,

        A o b’awon angeli korin.

        Ogo, ogo f’Oba wa,

        Halleluya, Halleluya,

        A o ‘duro, o, niwaju Re.  Amin


English »

Update Hymn