1. E mura ke sin ni ‘jo yi,
Ijo mimo kan ni
Ijo eleyi ni yio wa,
titi aiyeraiye
Cr: E foribale fun,
E foribale fun,
E foribale fun Baba,
Oba awon oba.
2. E mura ke sin mi ‘jo yi,
Ka le ye nikehin,
E foribale fun Baba,
Oba awon oba,
Cr: E foribale fun,
E foribale fun,
E foribale fun Baba,
Oba awon oba.
3. Ayo, Ayo, yio po,
Ninu Ijo Mimo yi,
Ijo yi ni yio gbaiyela,
L’ojo mimo t’awi
Cr: E foribale fun,
E foribale fun,
E foribale fun Baba,
Oba awon oba. Amin