HYMN 731

1.	E gbe ori nyin si oke e,

	Ani enyin, enu ona

	Ki a si gbe nyin si oke e,

	Enyin ‘lekun aiyeraye.

Chorus:	K’oba ogo wo inu ile,

	Wo ‘nu ile mimo Re wa,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jehovah ni Oba Ogo,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jesu Kristi Olugbala.


2.	E se l’Oba enyin enia Re,

	Ki gbogbo araiye se l’Oba,

	Ki e si ma fi i ayo sin,

	F’ayo fi sin tokantokan, 

Chorus:	K’oba ogo wo inu ile,

	Wo ‘nu ile mimo Re wa,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jehovah ni Oba Ogo,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jesu Kristi Olugbala.


3.	Agbara Emi Mimo se tan,

	Lati wa gunwa ninu wa,

	E fi okan Mimo ke pe e,

	Ke pe ninu ‘le Mimo Re.

Chorus:	K’oba ogo wo inu ile,

	Wo ‘nu ile mimo Re wa,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jehovah ni Oba Ogo,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jesu Kristi Olugbala.


4.	E fi iwa Mimo ati ife,

	Sin Oba wa ‘rinu rode,

	Olumoran okan araiye,

	Yio si gbo ohun igbe wa,

Chorus:	K’oba ogo wo inu ile,

	Wo ‘nu ile mimo Re wa,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jehovah ni Oba Ogo,

	Ta ha ni Oba Ogo na?

	Jesu Kristi Olugbala.  Amin



English »

Update Hymn