HYMN 737

1.  MALEKA Mimo,

     Won nt'Orun sokale wa,

     Nipa ore ofe Olugbala,

     Won nyi ite Re ka.


2.  St. Gabriel Onibode,

     On forin ayo yin won,

     Eje ka ko orin mimo,

     Orin ope f’ Oluwa.


3.  E je ka f’okan wa sokan,

     F’ope f’Olugbala,

     Nitori t’Oluwa mbe,

     Pelu wa n’gba gbogbo.


4.  Maleka oniye mefa,

     Won nfi meji wole,

     Won nfi meji boju,

     Won nfi meji yin

     Oluwa.  Amin


English »

Update Hymn