HYMN 74

1.	Eyo, e yo, e yo

	Enyin omo ‘Jo Mimo

	Ayo ni Baba wa,

	E yo, e yo, e yo.


2.	E mura sesin yi,

	Enyin omo ‘Jo Mimo

	Esin yi yio bori,

	E yo, e yo, e yo.


3.	Igba ‘kehin na de,

	Enyin omo ‘Jo Mimo,

	E di Oluwa mu,

	E yo, e yo, e yo.


4.	Aiye yi le sin wa,

	Enyin omo ‘Jo Mimo,

	E mura sesin yi,

	Ke ba le ri Baba

	E yo, e yo, e yo.

5.	Ajinde ni Baba,

	Baba wa orun wa,

	Ologo meta ni,

	E yo, e yo, e yo.

6.	Ninu ayo lawa wa,

	Awa Maleka Orun

	Ayo ninu Kristi,

	Ayo, ayo, ayo.

7.	Awon agutan Jesu,

	E si ‘se Baba nyin,

	ayo yin yio si po,

	ninu Kristi Jesu.

8.	Ijo Mimo Orun,

	T’aiye ‘yio gba aiye la,

	E si ‘se Oluwa,

	K’aguntan le po si

9.	E f’ogo f’Oluwa,

	Enyin omo ‘Jo Mimo,

	Ogo ni fun Baba,

	Ogo, Ogo, Ogo.		Amin

English »

Update Hymn