HYMN 741

IFE tani awa fi wa laiye?

Ife Jesu ni awa fi wa laiye,

Ife tani awa fi wa laiye

Ife Jesu ni awa fi wa laiye,

Tani ka f’ope fun?

Jesu ni ka f’Ope fun,

Tani ka f’ope fun?

Jesu ni ka f’ope fun

Ka foribale fun,

Ka f’okan bale fun

Ka foribale fun,

Ka f’okan bale fun,

Ife Jesu ni awa fi wa laiye. Amin

English »

Update Hymn