1. ENYIN Omo‘Jo Mimo,
E busayo ninu ‘Jo Mimo,
Nitori Ife Re pelu wa,
Enyin omo 'Jo Mimo,
E busayo ninu ‘Jo Mimo
Nitori ife Re mbe fun wa.
2. E ma korin e majo,
Ke si mayo ninu ‘Jo Mimo,
Nitori ife Re pelu wa,
Ema korin e majo,
Ke si mayo ninu 'Jo Mimo,
Nitori ife Re mbe fun wa.
3. Nitori ‘danwo ba de,
Ke mayo ke si gbadura,
Nitori ife Re, pelu wa
Nigbati ‘danwo ba de,
Ke mayo ke si gbaura,
Nitori ife Re mbe fun wa. Amin