HYMN 761

1.  ENYIN Ogun Mimo t’Orun,

     Oluwa Baba wa Orun,

     Emi Mimo wa wonu wa,

     Mimo, Mimo, Mimo, Mimo.


2.  Enyin Ogun Mimo t’Orun,

     Mimo Mimo Baba wa Orun,

     Baba Mimo wa we awa,

     Elese nu, Baba wa Orun.


3.  Enyin Ogun Mimo t’Orun,

     Mimo,Mimo lat’ Orun wa,

     Mimo, Mimo l’awon Angeli
 
     nko.  Amin


English »

Update Hymn